The Chairmanship Aspirant of Abeokuta South Local Government, Hon. Olujimi Adekunle David popularly known as DESMOND has felicitated with the paramount ruler of Egbaland Oba Dr Adedotun Aremu Gbadebo OON on the occasion of his 15th coronation anniversary.
According to his congratulaton message, Happy 15th Coronation Anniversary to His Royal Majesty, Oba (Dr) Adedotun Aremu Gbadebo, CFR. (Okukenu IV). The Alake and Paramount Ruler of Egbaland
Kabiesi Omo ara ake majo meji
Omo ajogberu ma jo gbeko
Omo eru ni sin ni, eko kii si ni niyan
Omo abilake igangan
Omo eluku sawo lolo
Omo ologbedu bariba
Iyi won n fawo seri toun akete ati erin
Omo bo le peja, ko peja
Omo bo le parogidigba ko parogidigba
Mo pa igangan olodo afara dudu wowo
Omo abilake ko nje igangan
Omo oloka merindinlogun
Omo elere mefa
Omo subulade
Omo agbade loba lori
Omo arose foba je
Omo lakesi
Omo osan la nbinu
Omo oru la a seka
Ika ti a ba se losan ko gbeni
Lakesi omo a'orisa lofin
Ki a ma gbohun agogo
Omo oba laganran
Omo oloti iddo, omo ajirotutu
Oba ni won nje nile Alake majo
Omo jeun tan o fawo
Omo ta tan o foja
Omo koja o begi dina
Ogbe o meni o ko o
Kabiesi oo....
No comments